Yoruba people wa lara eya to funny ju😂
Won ni afiwe ti ko ni rival pelu ara orisirisi.
Can you imagine wipe kosi ona ti eeyan legba ma jẹbi ọrọ especially if
you are the younger one.
3. Ta lo gbe enu e soro? Amẹbọ
4. Se won bi e? Olofofo
5. Da pada fun omo yen joo. Agbaya
6. And you left him behind all alone? Ọdaju
7. Why do you finish it all? Onijekujẹ
8. Mo ti n pe e lataaro. Eleti ikun
9. Brown ni moni koo gbe not blue. Alagbọya
10. Stop talking. Alabẹbẹ
11. Ni bo ni traffick wa? Onirinkurin
12. Lo we joo. Oloorun
13. Can’t you lift that small bag? Ọlẹ
14. (After two call out) O n kami l’ohun abi
15. You won’t remembaa. Alakogbagbe
16. Put it down. Ọde
17. #200 for snacks? Onijekuje
18. Stop stepping on that bowl now. Apa
19. Stop pinching that doy. Ika
20. Is that what I sent you?. Oponu
21. But you’ve just eaten. Tifun lọran
22. And you are hungry again, olonje iya
23. Don’t carry it like that now, Basejẹ
24. O tii wẹlataa rọ! Ọbun
25. You don’t know 8-5. Olodo
26. You are too stubborn. Alagidi osi
27. You been playing game since. Ko mọ jere lọ.
28. Won’t you return it? Abunu
29. Is it me you’re doing that too? Onibaje
30. Leave me jọọ. Alainisẹ
31. You are so funny. Oniyẹyẹ
No comments:
Post a Comment